I Am Me….. I Love My Culture

Orúukòo miì ni ADENIKE DANIELA TAIWO
Omo bíbí ìlú Òkèigbó ní ìpínlè Ondo ni mí.
Omo Yòrùbá pónmbélé ni mo jé.


I love my culture.. I love my homeland
I am the daughter of the source
I am like a clear river which flows
My ancestors were strong warriors
Dérin Ológbénlá the fearless warrior from Ilé-ifè is my great grandfather.


My Skin is like a halogen lamp; Sharp and bright
Caramel brown yet beautiful like a wild rose
Bronzed in Elegance
Enameled with grace.


Omo ilé Odò eléyowó ni Bàba tóbí Baabàmí, Àree Kúgbàyígbé naani ìyá Baabàmi Bàbá iyami Àree nàni, Àree Áfìdípòtè nani Bàba ìyá mi Omo OBA ni mojé (I am a princess).
Èmí lomo olókè kan àríjó
Omo olókè kan àríyò
Omo Òkèigbó elépó
Emí omo afi ojó gbogbo dáàrà bí egbin.


Òkèigbó ají gbó tèsó, ají gbó toge
Òkèigbó elépo… Tóobá fàyà gbámi láyà ádìjà…
Òkèigbó elépo.


I am unapologetically me.
I am ADENIKE TAIWO.. Friends call me Lanicky.

Who are you?


Location: Oloori river, Òkèigbó.

Related posts

Leave a Comment